Àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Awọ alángba inú iyẹ̀pẹ̀
Gecko olórí funfun kúkuru tí ìrù rẹ̀ kúrú
Awọ alángba inú iyẹ̀pẹ̀

Àkójọ àwọn ẹranko afàyàfà àwon ẹranko elégungun tó wà ní ọ̀wọ́ àwọn ẹbí ẹranko afàyàfà, tí ó dé àwọn ọ̀wọ́ ńlá mẹ́ta

Ìhà ẹgbẹ́ Anapsida[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ètò Testudines - Àwọn Ìjàpá[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ìhàètò Cryptodira
    • Ẹbí Chelydridae
    • Ẹbí Emydidae
    • Ẹbí Testudinidae
    • Ẹbí Geoemydidae
    • Ẹbí Carettochelyidae
    • Ẹbí Trionychidae
    • Ẹbí Dermatemydidae
    • Ẹbí Kinosternidae
    • Ẹbí Cheloniidae
    • Ẹbí Dermochelyidae
  • Ìhàètò Pleurodira
    • Ẹbí Chelidae
    • Ẹbí Pelomedusidae
    • v Podocnemididae