Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Coordinates: 46°14′N 06°03′E / 46.233°N 6.050°E / 46.233; 6.050

Nínú ọ̀dẹ̀dẹ̀ ẹ̀rọ ìmúsáré
Large Hadron Collider
(LHC)
LHC experiments
ATLASA Toroidal LHC Apparatus
CMSCompact Muon Solenoid
LHCbLHC-beauty
ALICEA Large Ion Collider Experiment
TOTEMTotal Cross Section, Elastic Scattering and Diffraction Dissociation
LHCfLHC-forward
MoEDALMonopole and Exotics Detector At the LHC
LHC preaccelerators
p and PbLinear accelerators for protons (Linac 2) and Lead (Linac 3)
(not marked)Proton Synchrotron Booster
PSProton Synchrotron
SPSSuper Proton Synchrotron

Àdàkọ:Hadron colliders

Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà tabi Large Hadron Collider (LHC) ni ero imusare eruku pelu okun totobijulo ati togajulo lagbaye. Ó jẹ́ kíkọ́sókè látọwọ́ CERN láti ọdún 1998 dé 2008, pẹ̀lú èrò láti gba àwọn aṣefísíksì láyè láti ṣe àdánwò ìsọtẹ́lẹ̀ àwọn orísi àròjinlẹ̀ físíksì eruku àti físíksì olókun-gíga, àti àgàgà láti wá bọ́yá bósónì Higgs wà lóòótọ́[1] àti orísirísi àwọn eruku tuntunàjọbáramu adárajùlọ ṣe àsọtẹ́lẹ̀.[2] Ìrètí ni pé LHC yíò wá ìdáhùn is expected to address some of the ọ̀pọ̀ àwọn ìbérè inú físíksì, nípa èyí láti mú ìlọsíwájú bá òye àwọn òfin àdánidá jínjnlẹ̀. Ó ní ẹ̀rọ ìwárí mẹ́fà tí ìkọ̀ọ̀kan wà fún ìwàdìí ohun pàtó kan.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Missing Higgs". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10. 
  2. "Towards a superforce". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10.