Ọlagunsoye Oyinlọla

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Ọlagunsoye Oyinlọla

Olagunsoye Oyinlola (left) with Femi Fani-Kayode at a reception in 2007
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí February 3, 1951
Okuku, Odo Ọtin LGA, Ọṣun State
Ọmọorílẹ̀-èdè Nigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlú PDP

Ọlagunsoye Oyinlọla (ojoibi February 3, 1951) je omo ologun to tifeyinti ati oloselu omo ile Naijiria. Lowolowo ohun ni Gomina Ipinle Osun lati 29 May, 2003 de 26 November 2010[1] nigbati ile-ejo fagile idiboyan re sipo fun igba keji gege bi gomina ninu idiboyan 2007.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]