Ọrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọrùn
Ọrùn ènìyàn
Latin collum
Dorlands/Elsevier Ọrùn

Ọrùn jé èyà ara tó so orí pò mó ara, ó le jé ní ènìyàn tàbí eranko. Orùn ní ó n gbé orí dúró, inú rè sì ni isan tí ó n mú orí yí si sotun-sosi wà.[1]

Orùn se idabobo fún apá kan òpá èyìn àti àwon nafu ara kòkan tí oun lo látorí orsí àwon èyà ara mír, orùn sì tún jé idabobo àti ònà fún àwon ohun èlò èjè tí oun lo sí orí àti èyi to ún padà sáyà.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. <"The Key Muscle for Your Neck Function". Verywell Health. 2012-08-30. Retrieved 2022-02-23.