Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Ogbomosho

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ogbomosho North
Ogbomosho palace
Ogbomosho palace
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilAkanji Kabir Ayoade (PDP)
Area
 • Total91 sq mi (235 km2)
Time zoneUTC+1 (WAT)

Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Ogbomosho jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Nàìjíríà, tí Olú ile ìṣẹ́ rẹ̀ wà ní òpópónà Ìlọrin tí alága wọn lọ́wọ́lọ́wọ́ sí jẹ́ ọ̀gbẹ́ni, kabir Àkànjí. Ìjọba ìbílẹ̀ yí jé ibi tí a gbé ọkàn lára ilé ìwé ẹ̀kọ́ gíga Ladoke Akintola University of Technology (LAUTECH) kalẹ̀ sí, ilé ìwé ẹ̀kọ́ ìwòsàn ló sì jẹ́ ní òpópónà Ìlọrin-ògbómọ̀ṣọ́ àtijọ́ .Ó sí tún jẹ́ ilé ìwé ẹ̀kọ́ ìwòsàn àwọn afọ́jú. Ààfin sòún tí ògbómọ̀ṣọ́ ni ilé ìsẹ̀m̀báyé ti ìlú náà.Apá àríwá Ògbómọ̀ṣọń ìjọba ìbílẹ̀ tí ènìyàn pọ̀ sí jùlọ ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, tí o jẹ́ ibi pàtàkì ọrọ ajé wọn tí ilẹ̀ rẹ̀ sí fẹ̀ tó if 235 km2.[1] òhun ni ìjọba ìbílẹ̀ tí o pọ̀jù ní ìpínlè òyó ni ọdún 2006 ní gbà tí wọn ṣe ètò ìkànìyàn.

Àmì ọ̀rọ̀ ìfi lẹ́tà ránṣẹ́ ni 210.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Adewuyi, Kehinde; Adeyemo; Adejumo (December 2018). "Use of GIS in production of soil series map in Oyo State, southwestern Nigeria". International Research Journal of Earth Sciences 6 (12): 12–21. ISSN 2321-2527. http://www.isca.me/EARTH_SCI/Archive/v6/i12/2.ISCA-IRJES-2018-019.pdf. 
  2. "Post Offices – with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on November 26, 2012. Retrieved 2009-10-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)