Aloysius Akpan Etok

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aloysius Akpan Etok
aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
2007–2015
ConstituencyÀríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 Oṣù Kejì 1958 (1958-02-15) (ọmọ ọdún 66)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
Professionolóṣèlú àti olùkànsí

Aloysius Akpan Etok jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2007 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Senator Etok's Biography". Senator Aloysius Etok. Retrieved 2009-09-22. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "A/Ibom, Rivers in Fresh Battle over NDDC’s Top Position". BusinessWorld. 2 July 2009. Archived from the original on 2013-01-19. Retrieved 2009-09-22.