Ayrton Senna

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ayrton Senna
Born(1960-03-21)21 Oṣù Kẹta 1960
São Paulo, Brazil
Died1 May 1994(1994-05-01) (ọmọ ọdún 34)
Bologna, Italy
Formula One World Championship career
Nationality Brazilian
Active years19841994
TeamsToleman, Lotus, McLaren, Williams
Races162 (161 starts)
Championships3 (1988, 1990, 1991)
Wins41
Podiums80
Career points610 (614)
Pole positions65
Fastest laps19
First race1984 Brazilian Grand Prix
First win1985 Portuguese Grand Prix
Last win1993 Australian Grand Prix
Last race1994 San Marino Grand Prix

Ayrton Senna da Silva (pèé [aˈiɾtõ ˈsenɐ da ˈsiwvɐ]  ( listen); Ọjọ́ ọ̀kànlélógún Oṣùkẹta Ọdún 1960 - Ọjọ́ kínín Oṣù karún Ọdún 1994) jẹ́ eléré ìdárayá awakọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Brazil[1][2] tí ó gba Formula One lẹ́ẹ̀mẹta ní world championships. Ó kú nígbà tí ó ń ṣíwájú nínú ìdíje 1994 San Marino Grand Prix. Ikú rẹ̀ ni ó kẹ́yìn nínụ ìdíje fún Formula One.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]