Orílẹ̀-èdè olómìnira onílànàìrẹ́pọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Constitutional republic)

Orílẹ̀-èdè olómìnira onílànà-ìbágbépọ̀ kan je ibijoba nibiti olori ibijoba ati awon oniseoba miran je asoju awon enia (ninu orile-ede olominira oseluarailu awon asoju yi je didiboyan latowo awon enia) won si gbodo sejoba gege bi ofin ilana-ibagbepo to wa to fa ala si agbara ijoba lori awon omoolu.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]