François Fillon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
François Fillon
Prime Minister of France
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
17 May 2007
ÀàrẹNicolas Sarkozy
AsíwájúDominique de Villepin
Minister of National Education
In office
31 March 2004 – 2 June 2005
Alákóso ÀgbàJean-Pierre Raffarin
Dominique de Villepin
AsíwájúLuc Ferry
Arọ́pòGilles de Robien
Minister of Social Affairs
In office
7 May 2002 – 31 March 2004
Alákóso ÀgbàJean-Pierre Raffarin
AsíwájúÉlisabeth Guigou
Arọ́pòJean-Louis Borloo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹta 1954 (1954-03-04) (ọmọ ọdún 70)
Le Mans, France
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnion for a Popular Movement
(Àwọn) olólùfẹ́Penelope Clarke
ResidenceHôtel Matignon
Alma materParis Descartes University
ProfessionLawyer
Signature

François Charles Amand Fillon (ìpè Faransé: ​[fʁɑ̃swa fijɔ̃]; ojoibi 4 March 1954 ni Le Mans, Sarthe) ni lowolowo Alakoso Agba ile Fransi. O je yiyansipo latowo Aare Nicolas Sarkozy ni ojo 17 May 2007.[1][2] O koko kosesile bi alakoso agba ni 13 November 2010 ki kabineti o to je tuntunda.[3][4]

Ni ojo 14 November 2010, Aare Nicolas Sarkozy tunyansipo pada bi alakoso agba.[5].


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Communiqué de la Présidence de la République concernant la nomination du Premier ministre" (in French). Élysée Palace. 2007-05-17. Retrieved 2007-05-17. 
  2. "Décret du 17 mai 2007 portant nomination du Premier ministre" (in (Faransé)). Legifrance.gouv.fr. Retrieved 2010-08-04. 
  3. French Prime Minister resigns before cabinet shuffle - The Globe and Mail
  4. "Ko si akole!!!". Archived from the original on 2010-11-15. Retrieved 2010-12-19. 
  5. "Sarkozy reappoints French prime minister amid cabinet reshuffle".