Gao

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gao
La Dune Rose and Gao city as seen from the top of the Tomb of Askia.
La Dune Rose and Gao city as seen from the top of the Tomb of Askia.
Country Mali
RegionGao
CercleGao Cercle
Elevation
226 m (744 ft)
Population
 (2005)[1]
 • Total57,989
Time zoneUTC+0 (GMT)
Gao, the Tomb of Askia.
Bozo Fisherman on the River Niger at Gao.

Gao je ilu kan ni orile-ede Mali bakanna o tun je oluilu fun Agbegbe Gao ni eba Odo Oya, iye awon eniyan ibe je 57,978 ni 2005.[1] Bakanna ohun tun ni oluilu ibi ayika ayika Gao.

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lati igba to ti je didasile, Gao je gbongan fun idunadura ati ikeko, bakanna o tun je oluilu fun Ile Obaluaye Songhai. O ri bi okanna, ati asa kanna mo awon ilu idunadura Kakiri-Sahara ni Timbuktu ati Djenne.


Coordinates: 16°16′N 0°03′W / 16.267°N 0.050°W / 16.267; -0.050

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Communiqué du Conseil des ministres du 3 janvier 2007