Isiaka Adetunji Adeleke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isiaka Adetunji Adeleke
Governor - Osun State
In office
January 1992 – November 1993
AsíwájúLeo Segun Ajiborisha
Arọ́pòAnthony Udofia
Senator - Osun West
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 2007
Arọ́pòMudasiru Oyetunde Hussein
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí15 January 1955
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
ProfessionBusinessman, Politician

Isiaka Adetunji Adeleke (15 January 1955 – 23 April 2017) jẹ́ òlòsèlú àti gómìnà ìpínlè Osun, orile-èdè Nàìjíríà, tí ò sí figbàkan ri jẹ omo Ilé Alàgbà Nàìjíríà tí o sojú ìpínlè Osun lemeji larin ọdún 2007 si 2011 labẹ àsìá ẹgbẹ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) tí wón si dibo yan lẹkan si lábẹ àsìá ẹgbẹ́ All Progressives Congress in 2015.[1]

Ìgbésíayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wón bí Isiaka Adetunji Adeleke ní ọdun 1955 sí ìdílé Ayoola Adeleke ati Esther Adeleke.[2]. Wọn bí ni [[ Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu|ìpínlè Enugu]]. Ó bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ alakobere ni Christ Church School, Enugu ki o to lọ́ si ìlú Ibadan.[2] Ọ́ parí ilé-ẹ̀kọ́ gírámà ní Ogbomoso Grammar School.[1][3][4]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Sen. Isiaka Adetunji Adeleke". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on November 23, 2009. Retrieved 2009-09-20. 
  2. 2.0 2.1 Lawal, Olumide. "Isiaka Adeleke: 60 years of service to humanity". sunnewsonline. Archived from the original on 5 January 2016. Retrieved 27 December 2015. 
  3. "Timi of Ede, Oba Oyewusi Agbonran II". The Nation. 2009-08-22. Archived from the original on 2011-07-26. Retrieved 2009-09-20. 
  4. "Davido mourns late Uncle, Senator Isiaka Adeleke". The Vanguard. April 24, 2017.