Jean-Paul Proust

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jean-Paul Proust.
Jean-Paul Proust
Minister of State of Monaco
In office
1 June 2005 – 29 March 2010
MonarchAlbert II
AsíwájúPatrick Leclercq
Arọ́pòMichel Roger
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí3 March 1940
Aláìsí7/8 April 2010 (aged 70)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
Alma materÉcole Nationale d'Administration

Jean-Paul Proust (3 March 1940 – 8 April 2010[1]) Jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ìlú Faransé àti Manegasque. O ṣiṣẹ́ sin ìlú Monaco gẹ́gẹ́ bí Mínísítà Ìpínlẹ̀ ti Monaco[2] tẹ́lẹ̀ rí.

Ìgbésí Ayée rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Jean-Paul Proust ní 3rd of March 1940 ní vaas, Srthe, Ní Faranse.[3] Ó kẹ́ẹ̀kọ́ gboyè ní École Nationale d'Administration.

Isẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó sisẹ́ fún ìjọba ilẹ̀ faransé fún ọjo pipe. Ose ise sin gege bi adari awon Guadelouoe lati Osu Kesan Odun 1989 si Osu keje Odun 1991 ati Olori olopa ilu Paris lati 2001 titi daa 6 December 2004 Leyin igba na lo sise sin gege bi minisita ti ipinle Monegasque, ipo ti o da bi Minisita ti o ga julo. Oni ore ofe lati se ibura wole sipo fun Om'Oba Kunrin Albert II gege bi Sovereign Prince of Monaco.[4] Odi ipo na mu lati Ojo Kini Osu Kefa Odun 2005 si Ojo Okondinlogbon Osun Keta Odun 2010, ti omo'ba ati Ijoba faranse si ti fi sipo fun bi osu meta seyin.

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 04.html "April 2010" Check |url= value (help). [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Jean-Paul Proust's obituary". Archived from the original on 2012-07-10. Retrieved 2011-07-09. 
  3. Jean-Paul Proust's obituary Archived 10 July 2012 at Archive.is
  4. Bremner, Charles; Keeley, Graham (18 November 2005). "A-list absentees spoil prince's big day". The Times. Retrieved 3 April 2010.