John Stuart Mill

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
John Stuart Mill

John Stuart Mill je amòye pataki ninu eto isuna, oselu, irori , akowe ati bebe lo. A bi ni ogun jo, osu karun 1806, o dagbere fun aye ni ojo keje osun karun, odun 1873 ni pentoville leba london, England. Baba re ni James Mill. o bere ise ni Ile ise East India ni omo odun metadinlogun. Oruko iyawo re ni Harriet Taylor ti oku ni 1865. O je okan ninu awon paliamenti ni Westminster ni 1865.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]