Ken Nnamani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ken Nnamani
National Senator for Enugu East
In office
May 2003 – May 2007
AsíwájúJim Nwobodo
Arọ́pòChimaroke Nnamani
President of the Nigerian Senate
In office
April 2005 – May 2007
AsíwájúAdolphus Wabara
Arọ́pòDavid Mark
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kọkànlá 1948 (1948-11-02) (ọmọ ọdún 75)
Enugu, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
Alma materOhio University
OccupationBusinessman

Kenneth Ugwu Nnamani je alagba asofin ile Nigeria tele to soju fun Ipinle Enugu lati 2003 de 2007. Omo egbe oloselu People's Democratic Party (PDP) loje. Ni 2005 o di Aare Ile Alagba Asofin Naijiria titi di 2007.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Gbenga Oke (7 May 2008). "Ken Nnamani - Taking Good Governance and Development to Greater Height". Vanguard. Retrieved 2009-10-06.