Kgalema Motlanthe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
His Excellency
 Kgalema Motlanthe

Igbakeji Aare ile Guusu Afrika
President Jacob Zuma
Asíwájú Baleka Mbete
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 19 Oṣù Keje 1949 (1949-07-19) (ọmọ ọdún 65)
Alexandra, South Africa
Ẹgbẹ́ olóṣèlú African National Congress
Tọkọtaya pẹ̀lú Mapula Motlanthe
Ẹ̀sìn Anglicanism

Kgalema Petrus Motlanthe (pìpè [ˈkx͡ɑ.lɪ.mɑ mʊ.ˈtɬ͡’ɑ.n.tʰɛ])[1] (bibi 19 July 1949) je oloselu ara ile Guusu Afrika to di Aare ile Guusu Afrika larin 25 September 2008 ati 9 May 2009, lati se imupari akoko keji Thabo Mbeki ti o siwo ise gege bi Aare.[2]

Lowolowo Motlanthe ni Igbakeji Aare si Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]