Milton Obote

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Apolo Milton Obote

Obote in 1960
2nd President of Uganda
1st Executive President
8th President of Uganda
Asíwájú Mutesa II of Buganda (non-executive) (1966)
Presidential Commission of Uganda (1980)
Arọ́pò Idi Amin (1971)
Bazilio Olara-Okello (1985)
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Kejìlá 28, 1925(1925-12-28)
Apac District, Uganda Protectorate
Aláìsí Oṣù Kẹ̀wá 10, 2005 (ọmọ ọdún 79)
Johannesburg, Gauteng, South Africa
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Uganda People's Congress
Tọkọtaya pẹ̀lú Miria Obote
Milton Obote in Leipzig, DDR, with Gerald Götting (right) and S. Oyaka (left) October 1960.

Apolo Milton Obote (December 28, 1925 – October 10, 2005[1]), je Alakoso Agba ile Uganda lati 1962 de 1966 ati Aare ile Uganda lati 1966 de 1971, lekansi leyin re lati 1980 de 1985. Ohun ni oloselu ara Uganda to lewaju ibe de ominira lati owo ijoba amunisin Britani ni 1962.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Birth and death date according to the headstone inscription on his grave