Mutesa Kejì Buganda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Èère Edward Mutesa II in Uganda
Mutesa II of Buganda
Kabaka of Buganda
Orí-ìtẹ́1939 - 1969
Orí-oyèNovember 19th, 1942 at Buddo
Ọjọ́ìbíNovember 19, 1924
IbíbíbísíMakindye, Uganda
AláìsíNovember 21, 1969(1969-11-21) (ọmọ ọdún 45)
Ibi tó kú síLondon, United Kingdom
ÌsìnkúKasubi Nabulagala
AṣájúDaudi Chwa II of Buganda
Arọ́pọ̀Muwenda Mutebi II of Buganda
Consort1. Naabakyaala Damali Catherine Nnakawombe, the Naabagereka
2. Lady Edith Kasozi
3. Omubiitokati Beatrice Kabasweka
4. Lady Kate Ndagire
5. Naabakyaala Sarah Nalule
6. Muzaana Nalwooga
7. Lady Nesta M. Rugumayo
8. Lady Kaakako Rwanchwende
9. Lady Winifred Keihangwe
10. Lady Ngatho
11. Lady Catherine Karungu
BàbáDaudi Chwa II of Buganda
ÌyáNamasole Irene Drusilla Namaganda

Major General Sir Edward Frederick William David Walugembe Mutebi Luwangula Mutesa II KBE (November 19, 1924 – November 21, 1969), jẹ́ Kabaka ti ilẹ̀ Buganda láti November 22, 1939 títí dìgbà tó fi kú. Òun ni Kabaka karùndínlógójì ti Buganda àti ààrẹ àkọ́kọ́ ti Uganda. Wọ́n máa ń pè é ní ọba tàbí Freddie.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]