Omoniyi Caleb Olubolade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Omoniyi Caleb Olubolade
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 30 Oṣù Kọkànlá 1954 (1954-11-30) (ọmọ ọdún 59)
Ipoti-Ekiti, AII Ijero, Ipinle Ekiti, Nigeria

Omoniyi Caleb Olubolade (ojoibi 30 November 1954) je Navy Captain totifeyinti ni ibise ologun ojuomi orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Bayelsa tele. O je yiyansipo Alakoso Ojuse Pataki ninu kabineti Aare Goodluck Jonathan ni 6 Osu Kerin, 2010.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]