Oro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Orò wà nínú àwọn àjọ̀dún ńlà tí àwọn Yorùbá ma ǹ ṣe ní ọdọọdún. Ọdún Orò jẹ́ ọọ̀kan pàtàkì nínú ọdún tí àwọn ẹ̀yà Yorùbá ma ń ṣe.

Oro si je osa kekere kan ti a mo si olorun ogun. Ara igi agbon lati gbe Oro jade. Osa nla gidi gan ni Oro je, won a si ma boo ni odoodun.

 

Oro je osa kan to sepe omo okunrin nikan lo le foju ri to si le boo paapaa julo lodo awon ti ajodun yii ba tan mo. A ki wo ni Oro fun eni ti ko ba n se omo oloro pelu fun obinrin lapaapo. Gbogbo obinrin pelu eni ti ko ba tan mo oloro ni lati wa ni asemo lasiko ti odun Oro ba waye. Ewe, obinrin o gbodo fi oju kan osa yi ti a n pe ni Oro. Bi obinrin ba foju kan Oro, Oro a gbe.

 

Orisirisi ona ara, asa ati ise ni awon oloro ma n gba se odun yii. Osi yato lati ipinle si ipinle ati ilu si ilu. Ni awon akoko miran, Oro a ma jade, tabi ki won gbe oro fun eni pataki bii oba to ba je olori awon to n boo orisa yii (Oro).

 

Bi Oro se bere

Ni aye atijo, osa merin kan wa ton n gbe ni Erekusu. Awon osa won yi so di mimo pe: Ta'aroa, Iyemoja (god of the sea), Tane, Oluigbo (god of the forest), Tu, (Jagunmolu atijo) ati Ro'o, (olorun nkan ogbin pelu bi oju ojo tinri). Awon onimose ti won tedo si agbegbe Polynesian tan esin won kakiri gbogbo igberiko Erekusu. Omu itesiwaju ba gbogbo agbaye àti idagbasoke si agbegbe ti ó je ti won gangan. Eleyi mu iyato ba nkan gbigbe awon ileto Polynesia. Ni agbegbe Ralatea, adari orisa Ta,aroa tin se ti olorun odo je ohun pataki erekusu odo fun orisa yi ti o wa lati da aye sile. Ohun ti a le salaye ninu e nipe, Arikiti je adari ijoye ati awon eniyan nlanlan ti Ralatea. Won tan ipinlese DE Taaroa. Lafikun, atun ripe awon alawo Oro ni ówò, bi omo Taaroa, Hina tu a uta, sibi marae, Taputapute nile Ralatea la fi lele. Gene bi isedale, Taputapute je idakeji ilu abinibi Oro.