René Préval

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
René Préval

President of Haiti
Aṣàkóso Àgbà Gérard Latortue
Jacques-Édouard Alexis
Michèle Pierre-Louis
Jean-Max Bellerive
Asíwájú Boniface Alexandre
Arọ́pò Michel Martelly
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 17 Oṣù Kínní 1943 (1943-01-17) (ọmọ ọdún 71)
Cap-Haïtien, Haiti
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Lespwa
Tọkọtaya pẹ̀lú Geri Benoit (Divorced)
Solange Lafontant (Divorced)
Elisabeth Delatour (2009–present)
Alma mater College of Gembloux
Catholic University of Leuven
University of Pisa
Profession Agronomist

René Garcia Préval (pípè ní Faransé: [ʁəne pʁeval]; born January 17, 1943) je oloselu ara orile-ede Haiti to je Aare orile-ede Haiti lati May 2006 de 14 May, 2011. Teletele, o tun ti je Aare lati February 7, 1996, titi di February 7, 2001, ati gege bi Alakoso Agba lati February 1991 titi di October 11, 1991.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]