Richard Francis Burton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sir Richard Francis Burton
Sir Richard Burton, portrait by Frederic Leighton, National Portrait Gallery
Ọjọ́ìbí(1821-03-19)19 Oṣù Kẹta 1821
Torquay, England
Aláìsí20 October 1890(1890-10-20) (ọmọ ọdún 69)
Trieste, Austria-Hungary
Resting placeSt. Mary Magdalen's Church, London, England
Orílẹ̀-èdèEnglish
Gbajúmọ̀ fúnExploration, Writing, Languages, Orientalist
Olólùfẹ́
Isabel Burton (m. 1861–1890)

Sir Richard Francis Burton KCMG FRGS (19 March 1821 – 20 October 1890) je omo ilegeesi to je olukowe, onimo-ileabinibi ati onimo-ede ati diplomat. O gbajumo fun awon irinajo re ati irnkerindo re ni Afrika ati Asia ati imo re nipa opo asa ati ede. Awon kan so pe o mo ede Europe, Asia ati Afrika 29 so daada.[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Lovell (1998), p. xvii.