Saint Martin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saint Martin
Orúkọ àbínibí: Sint Maarten (Duki)
Saint-Martin (Faransé)

Sobriquet: The Friendly Island
Jẹ́ọ́gráfì
IbùdóCaribbean Sea
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.050°W / 18.067; -63.050Coordinates: 18°04′N 63°03′W / 18.067°N 63.050°W / 18.067; -63.050
Àgbájọ erékùṣùLeeward Islands, Lesser Antilles
Ààlà87 km2 (34 sq mi)
Ibí tógajùlọ414 m (1,358 ft)
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀Pic Paradis
Orílẹ̀-èdè
Kingdom of the Netherlands
Constituent country Netherlands Antilles
Island territory Sint Maarten
Ìlú tótóbijùlọPhilipsburg (pop. 1,338)
France
Overseas collectivity Saint Martin
Ìlú tótóbijùlọMarigot (5,700)
Demographics
Ìkún74,852 (as of January 1, 2007)
Ìsúnmọ́ra ìkún860

Saint Martin (Faransé: Saint-Martin; Duki: Sint Maarten) je erekusu amooru ni ariwailaorun Karibeani, bi 300 km (186 miles) ilaorun orile-ede Puerto Rico. Erekusu yi to je 87 km2 je pipin ni 60/40 larin Fransi (53 km2)[1] ati Netherlands Antilles (34 km2)[2]; ohun ni erekusu to kerejulo ti awon eniyan n gbe si ninu okun ti o je pipin larin awon orile-ede meji, eyi je be lati odun 1648.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. INSEE, Government of France. "Démographie des communes de Guadeloupe au recensement de la population de 1999". Retrieved 2009-01-27.  (Faransé)
  2. Central Bureau of Statistics Netherlands Antilles. "Area, population density and capital". Archived from the original on 2009-02-07. Retrieved 2009-01-27.