Èdìdí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Èdìdí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ọ̀pá àṣẹÀàrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Lílò1979 (Current incarnation adopted 1999)
CrestOn a wreath, Argent and Vert, an eagle displayed gules
EscutcheonBlazoned sable a pall wavy argent
SupportersTwo horses Argent
MottoUNITY AND FAITH, PEACE AND PROGRESS
UseOn documents from the president to Parliament, and as a symbol on presidential vehicles, lecterns, and other places

Èdìdí Ààrẹ Àpapọ̀ Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà (Seal of the President of the Federal Republic of Nigeria) ni ami-idamo onibise Aare ile Naijiria. O koko je lilo ni 1979 latowo Aare Shehu Shagari ni igba oselu keji to teribomi, o je kikoti latowo awon ijoba ologun larin 1983 titi de 1999. Edidi Aare pada si lilo leyin ti Naijiria pada si oselu ni 1999, o si n je lilo lati gba na lo.


Ijuwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Edidi Aare ile Naijiria duro lori Ami Opa Ase ile Naijiria. Ami Opa Ase Naijiria ni apata dudu pelu ila fuufun meji ti won pade bi leta Y. Awon wonyi duro fun awon odo meji ti won n san gba Naijiria koja: odò Benue ati odò Ọya. apata dudu duro fun ile didara nigbati awon esin legbe mejeji duro fun iyì. Àṣá duro fun okun, aso ila awo ewe ati funfun lori apata duro fun ogbin ile.







Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]