Sefi Atta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sefi Atta
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 1964 (ọmọ ọdún 60)
Ìpínlẹ̀ Èkó , Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdè
  • Nigerian
  • American
Ẹ̀kọ́
Iṣẹ́
  • novelist
  • short-story writer
  • playwright
  • screenwriter
Notable workEverything Good Will Come
Websitesefiatta.com

Sefi Atta (tí a bí ní oṣù kínní ọdun 1964) jẹ́ Olùkọ̀wé ará ìlú Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà.[1] Wọ́n ti túfọ̀ àwọn oríṣiríṣi èdè, wọ́n ti ka àwọn ìwé rẹ̀ lórí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀ má gbesì bi BBC, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn eré ìtàgé tí ó ṣe ni wọ́n ti tún ṣe káàkiri àgbáyé. Àwọn àmì ẹyẹ tí ó ti gbà ni Wole Soyinka Prize for Literature in Africa ti ọdun 2006 àti Noma Award for Publishing in Africati ọdun 2009.[2][3]

Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Atta ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-èdè Nàíjíría, ní oṣù kínní ọdun 1964, sínú ìdílé ọmọ márùn-ún. Baba rẹ̀, Abdul-Aziz Atta ni akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà títí di ìgbà tí ó fáyé sílè ní ọdun 1972, ìyá rẹ̀, Iyabo Atta ni ó tọ dàgbà.[4]

Ó lọ ilé-ìwé Queen's College ti ìpínlè Èkó, àti Millfield SchoolEngland. Ní ọdun 1985, ó gba àmì-èye B.A. degree ní Birmingham University.

Ó fé Gboyega Ransome-Kuti, Dókítá ìsègùn òyìnbó, àti ọmọ Olikoye Ransome-Kuti, wón sì bí ọmọbìnrin kan, Temi.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Sefi Atta – Short bio – Q&A (panellist) – Australian Broadcasting Corporation, 27 August 2012. Retrieved 2 September 2012.
  2. "Sefi Atta", Myriad Editions.
  3. Janine, "New: Acclaimed NOMA Award Winner Sefi Atta’s Latest Novel, A Bit of Difference" Archived 2015-08-23 at the Wayback Machine., Times Books LIVE, 22 August 2014.
  4. "Atta, Sefi 1964- | Encyclopedia.com". www.encyclopedia.com. Retrieved 2022-05-25. 
  5. "Atta, Sefi 1964–", Encyclopedia.com.