Shehu Musa Yar'Adua

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Shehu Musa Yar'Adua

Shehu Musa Yar'Adua (March 5, 1943 – December 8, 1997) je omo orile-ede Naijiria to je onisowo, jagunjagun ati oloselu. Nigba ijoba ologun Ogagun Olusegun Obasanjo, Yar'Adua ni o je igbakeji olori orile-ede gege bi Oga Gbogbo Omose Ologun[1]. Yar'Adua ku ni ogba ewon ni ojo 8 osu 12, 1997 leyin atimole re lowo ijoba ologun Ogagun Sani Abacha nitori akitiyan re fun ijoba arailu.

Shehu Musa Yar'Adua ni egbon Aare Naijiria tele Umaru Yar'Adua.

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Yar'Adua wa lati ilu Katsina lati idile oba . Baba Musa Yar'Adua, je oluko,won je oye Minisita fun ọrọ Eko lati 1957 si 1966 nigba Naiijiria Orilẹ -ede Akọkọ won je oye Tafidan Katsina ni ilu Katsina ati Mutawallin Katsina (keeper of the treasury). Baba to bi baba Yar'Adua's , Malam Umaru je Mutawalli, aburo e Umaru Yar'Adua, je olori ede ti Naiijiria lati 2007 to 2010 .

Yar'Adua ka ile-ẹkọ ni Sẹkọndiri Katsina Middle School ati Katsina Provincial School (ti je Government College, Katsina) awon ati Muhammadu Buhari jo je ọmo ile -iwe naa.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Biography of Sheu Musa Yar'Adua [1]