Taofeek Oladejo Arapaja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taofeek Oladejo Arapaja
Igakeji Gomina Ipinle Oyo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 29, 2007
GómìnàAdebayo Alao-Akala
AsíwájúAdebayo Alao-Akala
Asoju Ile-Igbimo Asofin
In office
May 29, 2003 – May 29, 2007
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíIbadan, Oyo State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP

Taofeek Oladejo Arapaja je oloselu omo ile Naijiria ati Igbakeji si Gomina Ipinle Oyo, Adebayo Alao-Akala lati 2007. Teletele, o je asoju ni Ile-igbimo Asofin Naijiria fun Ibadan South-West/Ibadan North-West Constituency lati 2003 de 2007 ati Alaga, Agbegbe Ijoba Ibile Guusu-Iwoorun Ibadan ni 1999 de 2003.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Iforowanilenuwo ni 2005 [1]