Yunifásítì ìlú Ilorin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilé-ìjọsìn Chapel of Light, Fáṣítì Ìlọrin.
Yunifásítì ìlú Ilorin

Yunifásítì ìlú Ilorin jé yunifásítì tí ijoba tí o wà ní ìpínlè Kwárà, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A dá yunifásitì ìlú Ìlorin kalè ni odún 1975 [1]. Orúko olori Yunifásitì Ìlorin lówólówó ni Ojogbon Wahab Olasupo Egbewole[2]. Yunifásitì Ilorin ní olé ní aadota egbèrún akeko [3] o si tun ní olé ni egbèrún meedogun hectare ile(15, 000 hectares), èyi tí o mu won je Yunifásitì tí o ni ilè jù ní orílè-èdè Nàìjíríà [3]..




Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "University of Ilorin". Times Higher Education (THE). 2021-11-21. Retrieved 2022-03-02. 
  2. https://punchng.com/just-in-unilorin-appoints-new-vice-chancellor/
  3. 3.0 3.1 Olusunle, Tunde (2021-11-20). "The Unilorin 'better by far' basket and one bad apple". TheCable. Retrieved 2022-03-02.