Yunifásítì ìlú Jos

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yunifásítì ìlú Jos

Yunifásítì ìlú Jos jé yunifásítì ìjoba ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó bèrè bí ogba yunifásitì ìlú ibadan ní osù kokanla, odún 1971 [1]. Ní odun 1975, ìjoba ologun ìgbànáà da kalè gegebi yunifásitì, òjògbón Gilbert Onuaguluchi sì jé olori àkókò yunifásitì náà [1]. Orúko olori yunifásitì náà lówólówó ní Òjògbón Tanko Ishaya [2]





Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "University of Jos History". University of Jos. 1978-10-01. Archived from the original on 2022-03-05. Retrieved 2022-03-04. 
  2. "UNIVERSITY OF JOS GETS NEW VICE CHANCELLOR". CVC | Committee of Vice Chancellors of Nigerian Universities. 2021-11-17. Retrieved 2022-03-05.