Zhu Guangya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fọ́tò àtijọ́ ti àwọn olókìkí onímọ̀-ìjìnlẹ̀ mẹ́rin ọmọ ilẹ̀ Chinisi

Zhu Guangya (Chinese: 朱光亚; December 25, 1924 - February 26, 2011) je asefisiksi inuatomu ara Ṣáínà ati oluko ni Chinese Academy of Sciences. Ohun lo je igbakeji alaga 8k ati 9k Chinese People's Political Consultative Conference (CPPCC).[1]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Biography of Zhu Guangya". China Vitae. Retrieved 27 December 2010.