Ìlá-Ọ̀ràngún

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ila Orangun)
Ìlá-Ọ̀ràngún
town
Country Nigeria
StateOsun State
Time zoneUTC+1 (WAT)
Ila Orangun
town
Ila Orangun is located in Nigeria
Ila Orangun
Ila Orangun
Coordinates: 8°1′N 4°54′E / 8.017°N 4.900°E / 8.017; 4.900
Country Nigeria
StateOsun State
Government
Time zoneUTC+1 (WAT)

Ìlá Òràngún (tàbí Ìlá) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú àtijọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀sun, Nàìjíríà. Ó jẹ́ olú ìlú àwọn ìlú àtijọ́ tó jẹ́ orúkọ kan náà ní ìlú ìgbómìnà ti ará ilẹ̀ Yorùbá ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn ti orílẹ̀-èdè nàìjìríà. Ìlá Òràngún jẹ́ ìlú tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orírun ìlú tí wọ́n jọ ṣẹ̀ wá (àti orírun ) ti Òkè-Ìlá Òràngún, ó wà ní 7.5 miles (12 km) tí tí dé ilá oòrùn gúúsù.[1]

Ìtàn ṣókí nípa Ila-Orogun láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Ila Orogun.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]