Wole Ojo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Wọlé Òjó)


Wole Ojo
Ọjọ́ìbí(1984-06-06)6 Oṣù Kẹfà 1984
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor
Notable workThe Child

Wọlé Òjó ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹfà, ọdún 19884.(bí 6 Okudu 1984). Ójẹ́ òṣèré jẹ oṣere orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó dìlú mọ̀ọ́ká ní inú iṣẹ́ sinimá nílẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2009, lẹ́yìn tí ó gbé ipò kẹ́rin nínú ìdíje Amstel Malta Box Office.

Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó gba oyè ìmọ̀ ẹ̀kọ́ nínú iṣẹ́ Àtinúdá (Creative Arts) láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ìlú Èkó.

Àwọn eré-àgbéléwò rẹ̀ gbogbo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Fíìmù Ojúṣe Ọ̀rọ̀
2011 Maami Kashimawo Eré-oníṣe
2012 When Fishes Drown Tony Eré-oníṣe
2013 Conversations at Dinner Chidi Obi Eré-oníṣe
2014 Umbara Point Jelani Thriller
Perfect Union Steve Kadiri Eré-oníṣe
Brave Nathan Doga Fíìmù kékeré
2015 The MatchMaker Bryan fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
Out of Luck Seun Eré-oníṣe
7 Inch Curve Kamani Eré-oníṣe
2016 Beyond Blood[1] fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
Entreat[2] Segun Adeoye fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
2018 Bachelor's Eve[3] Uche Eré-oníṣe

Àwọn àmì-ìdánilọ́lá tí ó gbà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Olùgbà Èsì
2010 6th Africa Movie Academy Awards[4] Most Promising Actor The Child Wọ́n pèé
2014 City People Entertainment Awards[5] Best New Actor (Yoruba) Wọ́n pèé
2013 2013 Nollywood Movies Awards[6] Best Actor (Indigenous) Maami Wọ́n pèé
2015 2015 Africa Magic Viewers Choice Awards[7] Best Actor in a Drama Brave Wọ́n pèé
2015 Nigeria Entertainment Awards[8] Actor of the Year (Nollywood) Brave Wọ́n pèé

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Helen, Ajomole (17 February 2016). "Popular actor shares challenges faced as an entertainer". naij.com. Archived from the original on 31 July 2017. Retrieved 30 July 2017. 
  2. Izuzu, Chidumga. ""Entreat": Watch Dakore Akande, Alexx Ekubo, Sadiq Daba, Wole Ojo in star studded trailer". pulse.ng. Retrieved 30 July 2017. 
  3. Jayne Augoye (January 3, 2018). "Wole Ojo, Kehinde Balogun, Gbenro Ajibade star in new film, "Bachelor’s Eve"". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/nollywood/254320-wole-ojo-kehinde-balogun-gbenro-ajibade-star-new-film-bachelors-eve.html. 
  4. Alhassan, Amina (3 April 2010). "The Child wins 9 AMAA nominations". Daily Trust. Archived from the original on 31 July 2017. https://web.archive.org/web/20170731031115/https://www.dailytrust.com.ng/index.php/news/4948-mentally-retarded-found-among-plateau-pilgrims. Retrieved 30 July 2017. 
  5. "See Full List Of Nominees For 2014 City People Entertainment Awards Nominees List". Information Nigeria. 8 June 2014. 
  6. "O.C Ukeje, Gabriel Afolayan, Funke Akindele, Imeh Bishop Udoh lead nominees for Nollywood Movie Awards". Nigeria Entertainment Today. 28 September 2013. 
  7. "AMVCA nominees announced". DStv. 12 December 2014. Archived from the original on 17 April 2015. 
  8. "Voting opens for Nigeria Entertainment Awards 2015". The Guardian. 19 July 2015. http://guardian.ng/saturday-magazine/weekend-beats/voting-opens-for-nigeria-entertainment-awards-2015/. Retrieved 30 July 2017. 

Àwọn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Wole Ojo