Àtòjọ àwọn olórin ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí. Ẹ lè wo àtòjọ ìpín àwọn orin orílẹ̀ èdè náà ní ẹ̀ka 'Nigerian musical groups'.

0-9[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • 2face Idibia - Olórin hip hop àti R&B
 • 9ice - Olórin hip hop àti afropop

A[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • A-Q - Àwọn olórin hip hop ni:
 • Eedris Abdulkareem
 • Afrikan Boy - ̀olórin Ráàpù
 • Afro Candy - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Tope Alabi  - olórin Ẹ̀mí
 • Yemi Alade - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
 • Tony Allen
 • Eva Alordiah - olórin Ráàpù
 • Amarachi
 • Aramide - olórin Afro àti Jáàsì
 • Aṣa - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin
 • Cobhams Asuquo - olórin Sóòlù (soul)
 • Alhaji Àlàmú Tátalọ̀ - olórin ìbílẹ̀
 • Yinka Ayefele - olórin Gospel
 • Adewale Ayuba - olórin Fújì

B[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Ayinde Bakare
 • Banky W - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin
 • Adé Bantu
 • Korede Bello - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù,Orílẹ̀ àti Olùkọrin àti onílù
 • TY Bello - olórin Gospel
 • Blackface Naija - olórin Régè
 • Andre Blaze - olórin Ráàpù
 • Brymo
 • Burna Boy - olórin àlùjó Régè

C[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • CDQ -olórin Ráàpù àti Olùkọrin
 • Chidinma -  olórin Pọ́ọ̀pù
 • Celestine Ukwu -  olórin Highlife

D[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • D'banj - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Da Emperor - olórin Ráàpù ti ìbílè
 • Da Grin - olórin Ráàpù Yorùbá
 • I.K. Dairo
 • Timi Dakolo - olórin tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti Idol West Africa (2007)
 • Stella Damasus - olórin Sóòlù (soul)  àti R&B
 • Dammy Krane
 • Darey - olórin R&B àti Olùkọrin
 • Davido - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Yinka Davies - olórin  Jáàsì
 • Oliver De Coque
 • Safin De Coque - Olórin hip hop àti Ráàpù
 • Dekumzy - olórin R&B àti Highlife
 • Dice Ailes
 • Di'Ja
 • Tonto Dikeh - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Don Jazzy - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • D'Prince - olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù
 • Dr. Alban
 • Dr SID - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Duncan Mighty -  olórin Régè

E[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Frank Edwards -  olórin gospel
 • Omotola Jalade Ekeinde - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
 • eLDee - olórin Ráàpù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • Emma Nyra - olórin R&B
 • Emmy Gee - olórin Ráàpù
 • Alhaji Dauda Epo-Àkàrà - Àwúrèbe

F[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Falz -  olórin Ráàpù àti Olùkọrin
 • Majek Fashek - olórin R&B àti Olùkọrinàti Olùkọrin
 • Faze -  olórin R&B
 • Flavour N'abania - olórin Pọ́ọ̀pù àti Highlife

G[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Tonye Garrick - olórin R&B àti Olùkọrin
 • Adekunle Gold - olórin àti Olùkọrin
 • Ruby Gyang

H[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Harrysong - olórin àti Olùkọrin
 • Humblesmith -olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù

I[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

J[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Jesse Jagz - olórin Ráàpù
 • Tamara Jones - olórin R&B àti Olùkọrin

K[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Kcee
 • Peter King
 • Tunde King
 • King Wadada - olórin Régè
 • Kiss Daniel
 • Koker
 • Ayinla Kollington
 • Abiodun Koya Wọn bi ní (1980),olórin gospel, àti opera
 • Fela Kuti - olórin  jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin
 • Femi Kuti -  olórin jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin
 • Seun Kuti -  olórin jaasi, afrobeat, onílù àti Olùkọrin

L[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

M[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • M.I - olórin Ráàpù
 • M Trill -olórin Ráàpù
 • J. Martins - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • May7ven
 • Prince Nico Mbarga
 • Maud Meyer - olórin jáàsì
 • Mike Ejeagha - olórin Highlife
 • Mo'Cheddah -olórin Pọ́ọ̀pù
 • Mode 9 - olórin Ráàpù
 • Cynthia Morgan - olórin Pọ́ọ̀pù àti dacehall
 • Mr 2Kay
 • Mr Raw
 • Muma Gee - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
 • Muna - olórin Ráàpù

N[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Naeto C
 • Tunde Nightingale
 • Niniola - Afro-house artist
 • Niyola - olórin jáàsì ati sóòlù
 • Genevieve Nnaji - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Nneka - olórin Pọ́ọ̀pù ati sóòlù
 • Nosa - olórin gospel

O[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

P[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Patoranking -  olórin régè àti dancehall
 • Pepenazi -  olórin Ráàpù, Pọ́ọ̀pù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • Shina Peters - olórin Afro-Jùjú
 • Phyno - olórin Ráàpù ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • Praiz - olórin R&B àti Olùkọrin

R[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Reekado Banks - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Ruggedman - olórin Pọ́ọ̀pù àti Ráàpù
 • Runtown - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin

S[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

T[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Tekno Miles - olórin Afro-Pọ́ọ̀pùolórin R&B àti Olùkọrin
 • Terry G - olórin R&B,  Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
 • Timaya - olórin régè
 • Tiwa Savage - olórin R&B àti Olùkọrin
 • Tony Tetuila-olórin R&B àti Olùkọrin

U[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Sir Victor Uwaifo - olórin highlife

W[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Waconzy - olórin Pọ́ọ̀pù
 • Waje
 • Eddy Wata
 • Weird MC - olórin Ráàpù
 • Wizkid - olórin Pọ́ọ̀pù

Y[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • YCEE - olórin Ráàpù
 • Yung6ix - olórin Ráàpù

Ẹ̀ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Music of Nigeria

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]