Èdè Akpa
Ìrísí
Akpa | |
---|---|
Akweya | |
Sísọ ní | Central Nigeria |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 2000 |
Agbègbè | Benue State |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | Àdàkọ:Sigfig |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | akf |
Akpa (Akweya) jẹ́ èdè Domoid, tí wọn máa ń sọ ní Ohimini àti Oturkpo LGAs ni ìpínlè Benue ni Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.