Étienne Goyémidé
Ìrísí
Étienne Goyémidé | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Étienne Goyémidé 22 Oṣù Kínní 1942 Ippy, Central African Republic |
Aláìsí | 17 March 1997 | (ọmọ ọdún 55)
Orílẹ̀-èdè | Central African |
Iṣẹ́ | Writer, playwright, poet |
Ìgbà iṣẹ́ | 1976–1997 |
Étienne Goyémidé (22 Oṣù Kínní Ọdún 1942–17 Oṣù Kẹẹ̀ta Ọdún 1997) jẹ́ ònkọ̀wé àti ònkọ̀tàn eré ọmọ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Áfríkà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún kíkọ àwọn ìwé-ìtàn tí àkọ́lé wọ́n jẹ́ Le silence de la forêt àti Dernier Survivant de la caravane.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Etienne Goyémidé: République centrafricaine". Afri Cultures. Retrieved 21 October 2020.
- ↑ "Étienne Goyémidé (b. 1942)". Oxford Reference. Retrieved 21 October 2020.