Ìdìbò Gbogbogbòò Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà ní Ọdún 2007.

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa
ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀
Nàìjíríà
 

Ìdìbò gbogbogbòò ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni ọdún 2007 láti yan olórí orílẹ̀ ede ati ọmọ ilé ìgbìmò asòfin àpapọ̀ wáyé ni ọjọ́ kọkànlélógun , oṣù kerin, ọdún 2007.

Ìdìbò Gómìnà àti ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ti wáyé ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kerin náà .


Ìdìbò Gómìnà àti ilé ìgbìmọ̀ ìpínlẹ̀ ti wiye ana ati Apejọ Ipinle ti waye ni ọjọ 14 Oṣu Kẹrin.

Umar Yar' Adua ti ẹgbẹ́ òṣèlú àlábúradà (PDP) jáwé olúborí nínú ìdìbò Ààrẹ

Umar Yar' Adua ti ẹgbẹ́ òṣèlú àlábúradà (PDP) jáwé olúborí nínú ìdìbò Ààrẹ

Umar Yar' Adua ti ẹgbẹ́ òṣèlú àlábúradà (PDP) jáwé olúborí nínú ìdìbò Ààrẹ

aláríyànjìyàn, tí wọ́n sì búra fún un ní ọjọ́

Kọkàndínlógbọn, oṣù karùn-ún. Àwọn

alámójútó ìbò lágbáyé ìbò ọdún náà gẹ́gẹ́ bíi " ìbò tó burúkú jùlọ lágbáyé" pẹ̀lú

dídabarú ìbò, jàndùkú, jíjí àpótí ìbò gbé àti ideruba". [1]

Àgbétẹ́lẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ kẹrindínlógún, oṣù karùn-ún, ọdún 2006, àwọn ilé ìgbìmò asòfin dibò láti ṣe àtúnṣe ìwé òfin pé kí olórí orílẹ̀ èdè máa ṣàkóso ju ìgbà méjì lọ lórí àlèéfa. [2] Ààrẹ Olusegun Obasanjo ko lépa igba keta .Ní àfikún kò rí àtìlẹyìn Igbákejì rẹ̀ Atiku Abubakar. Ìpolongo àwọn olùdíje fún Olórí orílẹ̀ èdè wáyé ni ìpárí oṣù Kejìlá, ọdún 2006 àti ípàṣẹ fún àwọn ìbọn ìkọlù tó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta (50,000) níye láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ológun láti ṣètò ìdìbò létòletò lakoko idibo. [3] Umaru Yar'Adua jẹ́ olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú àlábúradà Peoples Democratic Party(PDP) àti Muhammadu Buhari tí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ alátakò All Nigeria Peoples Party (ANPP) . [4] Atiku Abubakar, Igbákejì Ààrẹ tó wà nípò kéde ní ọjọ́ karùn-ún dínlọ́gbọ̀n, oṣù kọkànlá, ọdún 2006 pé ohun yóò díje [5] Ó sì padà jáde gẹ́gẹ́ bíi olùdíje fun ipò Ààrẹ ti ẹgbẹ́ Action Congress ni oṣù Kejìlá. [6]

Àwọn Olùdíje[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àjọ elétò ìdìbò ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà INEC sọ pé Abubakar kò lẹ̀tọ́ láti díje látàrí ẹ̀sùn jìbìtì tí wọ́n fi kàn án. Ilé ẹjọ́ gíga ti pàṣẹ pé ìgbìmọ̀ náà kò lè yọ olùdíje kúrò, ṣùgbọ́n Ìgbìmọ̀ Àjọ Eleto Ìdìbò (INEC) sọ pé òfin ti dá irúfẹ́ olùdíje bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́ kọ́ láti díje tí wọ́n bá ti fi ẹ̀sùn kàn [7].

Ilé ẹjọ́ gíga míràn, ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn, pàṣẹ ní ìwòyí àjò elétò ìdìbò pe ó ní àṣẹ láti yọ olùdíje. Abubakar gbìdánwò láti rí ìwé ìdìbò nípasẹ̀ ilé ẹjọ́. Ninu

ẹjọ́ tó wà ní ilé ilé ẹjọ́ apex, ilé ẹjọ́ naa pàṣẹ pe Àjọ elétò ìdìbò (INEC) kò le è yọ olùdíje kúrò níbí ìdìbò látàrí àti wá ọ̀nà fún Abubakar láti díje. Ile ẹjọ́ tó ga jù lọ, ilé ẹjọ́ àgbà ti fìdí àṣẹ náà múlẹ̀ àti ṣíṣe àtúnṣe ìdíje Abubakar. [7]

Adebayo Adefarati, olùdíje fún ẹgbẹ́ kékeré Alliance for Democracy. saláìsí ni ọjọ́ kọkàndínlógbọn, oṣù keta, ọdún 2007 kí ó tó di ọjọ́ ìdìbò [8] Eléyìí fa ìdíwọ́ fún ìdìbò, nítorí òfin fàyè gba irú ìdádúró bẹ́ẹ̀ látàrí irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ tí àwọn ẹgbẹ́ tí ó ni olùdíje bá béèrè fún un; síbẹ̀sbẹ̀, agbẹnusọ fun Àjọ elétò ìdìbò (INEC) sọ pe idibo náà kò ní jẹ́ dídá dúró . [9] O ní ẹgbẹ́ náà lè yan olùrọ̀pò tí yóò díje . [10]

Ìṣàkóso[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ọmọ ológun pa kéré jù ní márùn-úndínlọ́gbọ̀n awon afura sí alákatakítí ẹ̀sìn Ìsìnláàmú ní ọjọ́ kejìdínlogun, nígbàtí wọ́n kọlu àgọ́ Ọlọ́pàá kan ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kẹrin ní kánò, ní ìdìbò ku ọjọ́ díẹ̀. Ó kù díẹ̀ kí ìdìbò bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlélógun, oṣù kerin ní àwọn kan gbìyànjú láti ṣekú pa Goodluck Jonathan olùdíje Igbákejì ààrẹ fún ẹgbẹ́ òṣèlú àlábúradà (PDP), àti gómìnà ìpínlẹ̀ náà ní ìpínlẹ̀ Bayelsa. Bákannáà igbìyànjú láti fi àdó olóró run ilé ise Àjọ elétò ìdìbò (INEC) ní ìlú Àbújá f'ori sánpọ́n.

[11][12]

Lẹ́yìn ìdìbò gómìnà àti ti ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kerin, àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú mejidinlogun pẹ̀lú ti Abubakar àti Buhari ni wọ́n ti bèèrè ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kerin pé kí wọ́n sún ìdìbò ààrẹ síwájú, kí wọ́n tú Àjọ elétò ìdìbò (INEC) ká, kí wọ́n sì fagile ìbò tó wáyé tẹ́lẹ̀; bí bẹ́ẹ̀ kọ́, wọ́n sọ pé kí wọ́n máa ni nkànkan ṣe pẹ̀lú ìdìbò ààrẹ. [13] Síbẹ̀síbẹ̀, ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹrin ọdún yìí, ẹgbẹ̀ òṣèlú Buhari (ANPP) àti Abubakar (AC) Action Congress sọ pé àwọn kò ní kó ìbò náà dànù . [14]

Àwọn ìwé ìdìbò ààrẹ mílíọ̀nù lọ́nà ọgọ́ta di títọ́jú sí orílẹ̀ èdè South Africa láti yàgò fún fífọwọ́kàn . [15] Sibẹsibẹ, ìyípadà kékeré ní ìkẹyìn láti ṣe àfikún Abubakar si

fa ìṣòro pínpín ìwé ìdìbò, tí ó sọ kún fa pípé dé ìwé ìdìbò títí di alẹ́ ọjọ́ Ẹtìi.[16] Awon ìwé àtúntẹ̀ kò ní nọ́mbà wọn ní sìs ẹ̀ntẹ̀lẹ̀ Àwọn ìwé ìdìbò ní mílíọ̀nù ọgọ́ta di kíkó pamọ́ sí orílẹ̀ èdè South Africa láti dènà fífọwọ́kàn. Síbẹ̀síbẹ̀, ìyípadà kékeré ní ìkẹyìn láti ṣáfikún Abubakar sí àkọjọ.

Àwọn alàfojúsí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lẹ́yìn ìdìbò ààrẹ, àwọn ẹgbẹ́ tí ń ṣe àmójútó ìdìbò náà kò dunnú sí ìgbẹ́léwọ́n ìdìbò náà. Olóye Max Van den Berg alámójútó láti Àjọ àgbáyé (European Union) ròyìn pé náà kò bá ìlànà àgbáyé mu àti pé ìlànà náà kò ṣe é gbẹkẹ̀lé. ń tọ́ka sí ìlànà ètò ìdìbò tí kò dára tó, àìní àkó yawọ́, àpẹẹrẹ ẹ̀rí jìbìtì, ìwà ipá àti ìrẹ́jẹ. Wọ́n ṣàpèjúwe ìdìbò náà gẹ́gẹ́ bíi èyí tó burúkú jùlọ lágbáyé pẹ̀lú dídabarú ìbò, ìwà-ipá, jíjí àpótí ìbò gbé àti Ìjayá. Àwọn ẹgbẹ́ alámójútó sọ pé ní ibùdó ìdìbò kan ní Yenagoa, ni gúsù ilẹ̀ epo, wọ́n ka ìbò ẹgbẹ̀rún méjì níbi tí ọgọ́rùn-ún márùn-ún ènìyàn ti forúkọ sílẹ̀ fún ìbò.

European Union àfojúsí si Max van den Bergòyìn pe ìdìbò náà kò sí ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ipilẹ àgbáyé àta tié ìlànà náà kò ṣe gbẹkẹ̀lé. ” [17] [18]ni agbaye”, pẹlu “iwadi ibo to gbilẹ, iwa-ipa, ji awọn apoti idibo ati ẹru”. [1] alafojusi sọ pe ni ibudo idibo kan ni Yenagoa, ni guusu ọlọrọ epo, nibiti eniyan 500 ti forukọsilẹ lati dibo, diẹ sii ju awọn ibo 2,000 ni a ka. [19]

O tún le ka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn itọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Nigerian election pushed back a week, CNN, 2011-04-03
  2. "Nigerian Senate Blocks Bid for 3rd Presidential Term", Washington Post . 16 May 2006.
  3. "Nigeria party picks its candidate", BBC News. 17 December 2006.
  4. "The candidates to be Nigeria's leader", BBC News. 22 December 2006.
  5. "Nigeria VP to run for president", BBC News, 25 November 2006.
  6. "Nigerian president withdraws VP's jet in feud", Reuters (IOL), 21 December 2006.
  7. 7.0 7.1 "Nigerian VP barred from elections - News". Al Jazeera. 2007-03-15. Retrieved 2022-11-18.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Al Jazeera 2007" defined multiple times with different content
  8. "Nigeria death fails to halt poll" (in en-GB). 2007-03-29. http://news.bbc.co.uk/2/hi/africa/6507813.stm. 
  9. "Nigerian presidential candidate from small party dies", Associated Press (International Herald Tribune), 29 March 2007.
  10. "Nigeria death fails to halt poll", BBC News, 29 March 2007.
  11. Salisu Rabiu: "Nigeria's military says troops kill 25 suspected Islamic militants days before election", newspress.com.
  12. "Attacks seek to derail Nigeria poll", Al Jazeera, 21 April 2007.
  13. "Vote boycott threat in Nigeria", Al Jazeera, 18 April 2007.
  14. "Nigeria poll boycott threat fades", Al Jazeera, 19 April 2007.
  15. "Nigerians tense on eve of polls", BBC News, 20 April 2007.
  16. "Slow start for Nigerian elections", BBC News, 21 April 2007.
  17. "Nigeria election 'worst ever seen'", SMH News, 24 April 2007.
  18. Tom Ashby, "Yar'Adua wins Nigeria poll 'charade'", Reuters (IOL), 24 April 2007.
  19. "Calls to cancel Nigeria poll result", Al Jazeera, 22 April 2007.