Jump to content

Òfin kòtò àkọ́kọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Photo of a backhoe that is over fifty percent submerged in a large hole that it dug in a peat bog before falling in.
Ọkọ̀ tí wọ́n fi ń gbẹ́lẹ̀ tí ó bá ara rẹ̀ nínú kòtò tí ó sì dáwọ́ gbígbẹ rẹ̀ dúró

Òfin kòtò àkọ́kọ́ tàbí Òfin kòtò jẹ́ òwe tí ó sọ wípé "tí o bá ba ara rẹ nínú kòtò, kí o maa ṣe gbẹ́ ẹ síwájú síi".[1][2]  Ìtumọ̀ rẹ̀ ni wípé tí o ba bá ara rẹ ní ipò tí kò dára, ki o dúró kí o sì ṣe àtúnṣe oun tí ò ń ṣe tẹ́lẹ̀ kí o má sẹ tẹ̀síwájú.

Ibi tí ó ti jẹyọ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oríṣiríṣi ibi ni wọ́n rò wípé òwe yìí ti jẹyọ. Ó yọjú nínú àtẹ̀jáde ojú ewé kẹfà ti The Washington Post ti ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹwá ọdún 1911, báyìí: "Kò ṣeéṣe kí ọlọ́gbọ́n ènìyàn bá ara rẹ̀ nínú kòtò, kí ó lọ ibiṣẹ́ kí ó sì tún maa gbẹ́ẹ lọ..."[3] Nínú The Bankers Magazine wọ́n ṣe àtèjáde rẹ̀ ní ọdún 1964 báyìí:"Jẹ́ kí n sọ fún ẹ nípa òfin kòtò:Tí o bá bá ara rẹ nínú kòtò, maa ṣe gbẹ́ẹ síwájú si."[4] Wọ́n sọ wípé Will Rogers, aláwàdà ará Amẹ́ríkà ni ó sọ ọ̀rọ̀ tí ó wà níwájú àmì ìṣafihan.[5]

Ní UK wọ́n pèé ní  "Òfin kòtò ti Healey àkọ́kọ́"[2] lórúkọ olóṣèlú Denis Healey, tí ó pòwe yìí ní ọdún 1980 àti lẹ́yìn ìgbà náà.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Apperson, George Latimer (2006).
  2. 2.0 2.1 Lloyd, John; Hargreaves, Ian (8 November 1996).
  3. Doyle, Charles Clay; Mieder, Wolfgang; Shapiro, Fred R. (2012).
  4. "Is That Dirt Being Shovelled?"
  5. Will Rogers Legacy.

Àwọn ìjápọ̀ látìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ní ṣe pẹ̀lú Denis Healey ní Wikiquote