Jump to content

Ẹ̀yà ara Ènìyan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Female and male adult human bodies, depicted without pubic or facial hair

Ẹ̀yà ara ni a tún lè pè ní àtò tàbí ìrísí Ọmọ Ènìyàn. Ẹ̀yà ara ọmọ ènìyàn yí kún fún oríṣiríṣi àti onírúurú (It is composed of many different types of sẹ́ẹ́lì) tí ó jẹ́ pé wọ́n kóra pọ̀ di tíṣù nínú ara, tí wọ́n si jọ di ẹ̀yà ara, àwọn wọ̀nyí ni wọ́n ń jẹ́ jẹ́ Kí homeostasis tíí ṣe àbójútó ara láti inú wá ó ṣiṣẹ́ déédé, àti láti jẹ́ kí ìṣẹ̀mí ọmọnìyàn ó rọgbọ nínú ara .

Ẹ̀yà ara ènìyàn tí a ń sọ yí ti bẹ̀rẹ̀ láti Orí, Ọrùn, Ọ̀fun níbi tí a ti lè rí Tááná tàbí Gògóngò tí ó lọ sínú Ikùn tàbí Inú), Apá, Ọwọ́, àti Ẹsẹ̀ tí ó parí sí àtẹlẹsẹ̀.

Ìmọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí ó níṣe pẹ̀lú ẹ̀ [[ẹ̀yà ara ènìyàn ni wọ́n ń pé ní anatomy, physiology, histology àti embryology. Àwọn Onímọ̀ nípa Physiology ni wọ́n ń kọ́ nípa báwo ni ara àti àwọn ohun to kórajọ di ara ní inú ṣe ń ṣiṣẹ́ sí. Ọ̀pọ̀ ẹ̀yà ara wọ̀n yí ni wọ́n ń ba ra sọ̀rọ̀, ba ra wọn ṣiṣẹ́ pọ̀ Ki ohun tí ó ń jẹ́ ọmọ ènìyàn ó to ma yan fanda, látàrí ohun tí wọ́n pé ní homeostasis. Homeostasis yí ni ó ń ṣàkóso lórí ìwọ̀n tí ó ya kí ṣúgà àti atẹ́gùn (oxygen) ó wá nínú ẹ̀jẹ̀ ọmọnìyàn .


Àdàkọ:TOC level