Jump to content

Ẹja

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ẹja
Akojopo ti Ẹja ninu omi
osunwon ti ẹja
akurakuda

Ẹja (fish), awon eja n gbé ninu omi. Won je orisirisi ẹja ati ẹranko ninu omi. Awa ni: àwọn erinmi, ótà òkun, eku ti odò ganganrangan, eku ti odò kekere, ẹja abániṣeré, akurakuda, ati ẹranko ti o poju! Won ni egungun. Àwon ẹja, won ni òsùwòn ati omodé ti won bi wa ninu ẹyin. Ninu omi, o je ìró, nitori naa, awon ẹja won ma lo iri-oju won diẹ-diẹ ati won ma gbiyanju lati gbó awon ohun, lati tówò, ati gbóòórùn. [1]

Ninu omi, o je orisirisi kemikali, ati omi o sise fun itanna. Opo ninu ẹja le ri isipopada dada, o rorun fun won. Lati se be, won lo iró ti o se pataki pèlú sensọ ti awa n pè "ila ti ina" (lateral line). Àwọn ẹja miiràn, won le ri ohun ọdẹ, sùgbón, bawo? Won ma lo idiyele itanna lati se e.[1]

Idi ọkan ti awa ni orisirisi ẹja ti o po gan je pé, omi bòó àádórin ni ọgórùn ti agbayé wa (70%). Àwọn ẹja yii, won gbé ni orisirisi ibugbé, won gbé ni okuta nisale okun ti iyùn, ojú-oró ti igbó, odò, odò-ṣiṣan, ati okun nla. Awa ni orisirisi iru ti ẹja, o je oké-o-le-egberun-mewaa-o-le-egbaa. (32,000). [1]

Àwọn ẹja, won le luwee jijinna jina ninu omi. Àwon eja salumoni tabi eja alawo pupa feere, won le lo si ibi kan losi ibomiran ti o jina gan! Lati ayika ti iyò si ayika ti omi tutù ati titun. Àwọn ẹja salumoni, won le luwee jijinna ti kilomita aadota ni ọjọ ọkan. Lati se be je dogba ti o ba sáré ìdíje eré-sísá ọlọ́nàjíjìn ni ọjọ ọkọkan. Jùmo ati lapapo, jijinna ti won ma gbékuro ati lúwèé je kilomita ẹgbẹ̀ẹ́dógún (5,000) lati okun nla si omi tutú ati omi titun won ma bi àwọn omodé. Jijinna won je ilàji ti jijinna ti Kanada! Ti o ba lo ọkọ, lati lo si ibi kan si ibi miiràn, ti jijinna ilàji ti Kanada o ma je dogba, o po gan o! [2]

Àwọn ẹja salumoni, won ko le gbékuro àjọ ti won ko wa olowè dara. Lati lúwèé sòkè ti odò, ko rorun o! Ko je ise-sise rorun, o soro gidigan, sùgbón awon ẹja salumoni, won le fò dada.[2]

  1. 1.0 1.1 1.2 https://www.nationalgeographic.com/animals/fish
  2. 2.0 2.1 https://spca.bc.ca/news/fun-facts-about-fish/