Jump to content

Ẹja ẹlẹsẹ mẹjọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kini Awon Ẹja ẹlẹsẹ mẹjọ?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
ẹja ẹlẹsẹ mẹjọ
Eja Elese Mejo
Eja Elese Mejo

ẹja ẹlẹsẹ mẹjọ ni ẹsẹ mejo, won ni ara riro ati agbon pelu agbara ti o po gan, sugbon wo ko ni ikarahun inu won. Awon eja elese mejo je eranko ti okun ati won je lokiki fun ara won yika ati roboto ati oju won ti wu sode, awa n ro nipa awon eja elese mejo dabi ibatan ati aburo re Ẹja ọlọ́wọ́ mẹ́wàá bi "Ewèlè ati Aderubaniyan ti Okun Jinle"[1] Die-die ninu awon eja elese mejo n gbé ni omi saijinle. Awon eja elese mejo je akàn, edé, alákàṣa, won je akurakuda pelu. Awon eja elese mejo won ma subu ati jabo lori ohun ode won ati lo apa won ti o ni agbara pupo ati mu ati gba eranko si enu won. Eja elese mejo o ma se iluwee sehin lokiki ati fifun ati lu omi pelu apakan ti ara re ti o ni agbara, awa n pe e «siphon». Awon eja elese mejo won ma rakòrò lori ile ati pakà ti okun nla, o ma fi ese re ni ile kekere lati ri ounje.

She ti gbo nipa Eja Elese Mejo Farawe?

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Eja elese mejo Farawe
Eja Elese Mejo Farawe

Eja Elese Mejo Farawe je oga ti parada ati etan, o le fi ara we dabi eranko miiran, o le dibon lati je eranko miiran sugbon awa n pe e «ayipada irisi» bee ni Eja Elese Mejo Farawe le yipada irisi re, o dara gidigan. O le dibon lati je eranko oloro tabi eranko pelu majele.[2] Eja Elese Mejo Farawe le yipada awo re pelu! Awon Eja Elese Mejo Farawe ni ogbon ti o tobi gan, o le se ara re alapin! O le yan eranko ti o fe farawe, o le sinku ati bo-mole ara re patapata ati fi awon apa re jade bi ese ti o le ta ati bu-san eranko. Awon eja elese mejo farawe, won mo awon ohun ti eranko ati eniyan miiran se yika won ni gbogbo asikò! Ese ti Eja Elese Mejo le je mita okan.

Lati jade, bo lowo, ati ye-kuro lati eranko apanirun tabi eranko ti o fe je won. Eja Else Mejo o ma luwee kiakia ni omi, fun po ara won ni ibi tabi aye kekere, parada, ati won le tu sile Aró ìkọ̀wé ti je ohun dudu ti o ma tankale ninu omi ati won ma saré fun igbesi aye won. Sugbon nitori won ti tu sile aro ikowé, awon eranko miiran, won ko le ri eja elese mejo. Bee ni, won ni ogbon ti o pupo o![3]

  1. https://kids.nationalgeographic.com/animals/invertebrates/facts/octopus
  2. https://octonation.com/octopedia/mimic-octopus/
  3. https://www.nwf.org/Educational-Resources/Wildlife-Guide/Invertebrates/Octopuses#:~:text=Octopuses%20use%20several%20different%20strategies,quickly%20propel%20themselves%20through%20water.