Ọkọ̀ ojú-omi Akérò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oko oju omi akero
Okó Ojú omi afàjè wà

Ọkọ̀ ojú-omi Akérò jẹ́ àgbàyanu ọkọ̀ akérò, akẹ́rù, tí ó lé rin irin-àjò káàkiri àgbáyé lórí alagbalúgbú omi. Ọkọ̀ ojú-omi akérò tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ohun ìrìnsẹ̀ tí ó ń ṣe ọmọnìyàn ní ànfàní pupọ̀, yálà fún iṣẹ́,okòwò tàbí ìṣèwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀. [1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Columbian Exchange Archived 2011-07-26 at Wikiwix". The University of North Carolina.