Jump to content

0.999...

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ninu Mathimatiiki 0.999... ( a tun le ko bayi tabi ) je nọ́mbà tóúnyípo to dọ́gba pére mo nomba 1. Lede miran ami-idamo «0,999...» ati «1» duro fun nomba gidi kanna.