Àrún èrànkòrónà ọdún 2019

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa àrún náà. Fún kòkòrò èràn tó ún fàá, ẹ wo: SARS-CoV-2.
Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta

Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (tàbí ní èdè gẹ̀ẹ́sí bíi Coronavirus disease 2019, COVID-19) jẹ́ àrún àkóràn kan tí èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró, èràn kòrónà irú 2 (SARS-CoV-2) ń mú wá.[1] Àrún náà kọ́kọ́ jẹ́ dídámọ̀ ní December 2019 ní Wuhan, ní China, to si ti ran ka gbogbo agbaye latigba naa pelu ajakale-arun kaakiriaye erankorona odun 2019-2020.[2][3] Ninu awon ami-aisan re to wopo ni iba, ikọ́, àti àìlèmín balẹ̀. Awon ami-aisan miran tun le je irora, hiha kelebe, igbe olomi, ikanra ona-ofun, ainlegbo oorun, ati irora ikun.[4] Botileje pe opo alaisan arun yi ni ami-aisan to loworo, awon miran le ni eran edo ati ikuna patapata opolopo ifun-ara.[5] Titi di ojo 3 April 2020, iye awon alaisan COVID-19 ti a mo lagbaye je 1,040,000, iye awon alaisi je 55,100 deaths.Iye awon ti ara won ti ya je 221,000.

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Naming the coronavirus disease (COVID-19) and the virus that causes it". World Health Organization (WHO). Archived from the original on 28 February 2020. Retrieved 28 February 2020. 
  2. "The continuing 2019-nCoV epidemic threat of novel coronaviruses to global health—The latest 2019 novel coronavirus outbreak in Wuhan, China". Int J Infect Dis 91: 264–66. February 2020. doi:10.1016/j.ijid.2020.01.009. PMID 31953166. 
  3. "WHO Director-General's opening remarks at the media briefing on COVID-19". World Health Organization (WHO) (Press release). 11 March 2020. Archived from the original on 11 March 2020. Retrieved 12 March 2020. 
  4. "Q&A on coronaviruses (COVID-19)". World Health Organization (WHO). Archived from the original on 20 January 2020. Retrieved 11 March 2020. 
  5. "Q&A on coronaviruses". World Health Organization (WHO). Archived from the original on 20 January 2020. Retrieved 27 January 2020.