ALDH16A1

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aldehyde dehydrogenase 16 family, member A1 tí a tún mọ̀ sí  ALDH16A1 jẹ́ aldehyde dehydrogenase gene.

Ìwúlò rẹ̀ fún ètò ìlera[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìyípadà nínú SPG21  (ACP33/maspardin) gene ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú mast syndrome, tí ó jẹ́ irú  spastic paraplegia. Protein tí ó ń kóòddù fún SPG21 gene ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú  ALDH16A1 enzyme.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Interaction of the SPG21 protein ACP33/maspardin with the aldehyde dehydrogenase ALDH16A1". Neurogenetics 10 (3): 217–28. January 2009. doi:10.1007/s10048-009-0172-6. PMID 19184135.