Abimbola Fashola
Abimbola Fashola | |
---|---|
First Lady of Lagos State | |
In role 29 May 2007 – 29 May 2015 | |
Governor | Babatunde Fashola |
Asíwájú | Oluremi Tinubu |
Arọ́pò | Bolanle Ambode |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹrin 1965 Ibadan, Western Region, Nigeria (now Oyo State, Nigeria) |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Babatunde Fashola |
Occupation |
|
Website | Official website |
Abimbola Fashola (wọ́n bíi ni ọjọ́ kẹfà osù kẹ̀rin ọdún 1965). Ó jẹ́ arábìnrin àkọ́kọ́ tí ìpínlẹ̀ Èkó àti ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀ rí Babatunde Fashola.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abimbola Emmanuela Fashola wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà osù kẹ̀rin ọdún 1965, ní ìlú Ìbàdàn, tí í se olú ìlú ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ní gúúsù-ìwọ̀-oòrùn Nàíjíríà.[2][3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé ní ilé-ẹ̀kọ́ Lagoon Secretarial College ní ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tó ti gba ìwé-ẹ̀rí Diploma. Ó padà gba ìwé-ẹ̀rí ìmọ́ ìjìnlẹ̀ nínú ìmọ̀-ẹ̀rọ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí àpapọ̀ ìlú Èkó.[4] Ó ṣiṣẹ́ díẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ̀ròyìn tó ń kọ́ṣẹ́ ní ilé-isẹ́ Daily Sketch kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ British Council ní ọdún 1987 ṣùgbọ́n ó kọ̀wé fipò sílẹ̀ lọ́dún 2006 nígbà tí wọ́n yan Babatunde Fashola ọkọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí asojú ẹgbẹ́ rẹ̀ àti olùdíje fún ipò Gómìnà ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "My love story with gov Fashola-Lagos first lady". Mynewswatchtimesng. Archived from the original on 23 April 2015. Retrieved 19 April 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Clement Ejiofor. "Abimbola Fashola Shares Her Love Story". Legit. http://www.naij.com/416167-abimbola-fashola-shares-her-love-story.html.
- ↑ "ABIMBOLA FASHOLA, SYMBOL OF HUMILITY". This Day Live. Archived from the original on 27 April 2015. Retrieved 19 April 2015.
- ↑ Aka, Jubril Olabode (2012). Nigerian Women of Distinction, Honour and Exemplary Presidential Qualities. Trafford. ISBN 9781466915541. https://books.google.com/books?id=A0I5gsKiDasC&dq=Abimbola+Fashola+Supported+her+Husband&pg=PA95.
- ↑ "I don't have an eye for politics but .. Abimbola Fashola". Vanguard News. 9 November 2012. Retrieved 19 April 2015.
- ↑ "CEO – LEADERSHIP EMPOWERMENT AND RESOURCE NETWORK" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 11 July 2023. Retrieved 2024-01-23. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)