Abor, Ghana
Ìrísí
Abor ( Abaw, Abↄ ) jẹ́ ìlú kan ní agbègè Kẹta Municipal ti Agbègbè Volta ní gúúsù ìla-orùn Ghana . Abor wà ní ìlà-orùn ti Odò Volta àti ní àríwá ti Keta Lagoon . Abor jẹ́ olókìkí fún Ilé-ìwé gíga Abor, nígbàgbogbo tí wọ́n máa npè ní ABORSCO. [1] [2] Ilé-ìwé náà jẹ ilé-ẹ̀kọ́ iyipo kejì.
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abor jẹ́ ilé àwọn ọmọ Anlo Ewe tí wọ́n ṣí lọ síbẹ̀ ní apá ìparí ọ̀rúndún kẹtàdínlógún. Wọ́n dá ìjọba Anlo sílẹ tí Abor jẹ́ apákan rẹ̀. [3]
Láti ìrisi ọ̀dọ̀ àwọn European Abor jẹ́ apá kan nínú àwọn Dutch "agbegbe ti ipa" Kẹta bẹrẹ ní nkán bí ọdún 1784, títí tí àwọn British fi gbàá tí ó sì ṣe pọ̀ sínú ìletò British Gold Coast, eyi ti o ti padà di Ghana.