Abraham Lincoln

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abraham Lincoln
16th President of the United States
In office
March 4, 1861 – April 15, 1865
Vice PresidentHannibal Hamlin (1861–1865)
Andrew Johnson (1865)
AsíwájúJames Buchanan
Arọ́pòAndrew Johnson
Member of the U.S. House of Representatives
from Illinois's 7th district
In office
March 4, 1847 – March 3, 1849
AsíwájúJohn Henry
Arọ́pòThomas L. Harris
Member of the Illinois House of Representatives
In office
1834–1842
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1809-02-12)Oṣù Kejì 12, 1809
Hodgenville, Kentucky, U.S.
AláìsíApril 15, 1865(1865-04-15) (ọmọ ọdún 56)
Petersen House,
Washington, D.C., U.S.
Resting placeLincoln Tomb, Oak Ridge Cemetery
Springfield, Illinois, U.S.
Ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Ẹgbẹ́ olóṣèlúWhig (1834–1854)
Republican (1854–1865)
Other political
affiliations
National Union (1864–1865)
(Àwọn) olólùfẹ́
Mary Todd
(m. 1842; his death 1865)
Àwọn ọmọRobert, Edward, Willie, and Tad
ProfessionLawyer
Politician
SignatureCursive signature in ink
Military service
Allegiance United States of America
Branch/serviceIllinois Militia
Years of service3 months
(April 21, 1832 – July 10, 1832)
Rank
  • Captain
    (April 21, 1832 – May 27, 1832)
  • Private
    (May 28, 1832 – July 10, 1832)
OBS:. Discharged from his command and re-enlisted as a Private.
Battles/warsBlack Hawk War

Abraham Lincoln (Listeni/ˈbrəhæm ˈlɪŋkən/; Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejì Ọdún 1809 – Ọjọ́ karùndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún1865) jẹ́ ààrẹ United States kẹrìndínlógún, tí ó ṣèjọba láti Oṣù kẹta Ọdún 1861 dí Oṣù kẹrin Ọdún 1865 tí wọ́n ṣekú paá. Lincoln jẹ́ olórí orílẹ̀ èdè United States nígbà ogún abẹ́lé ìlú náà —Ogun ìtàjẹ̀sílẹ̀ tí ó pọ̀ tí ó jẹ́ tí ìtẹríba, òfin àti rògbòdìyàn òṣèlú.[1][2] Ní ogun jíjà yìí ó dá ìṣọ̀kan sí, ó fi òpin sí òwò ẹrú, fún ìjọba lágbára, ó sì jẹ́ kí ìlọsíwájú bá okòwò ìlú.

Wọ́n bíi ní Hodgenville, Kentucky, Lincoln dàgbà sí ìwọ oòrùn frontier ní  Kentucky àti Indiana. Ókpọ ara rẹ̀ ní ìwé, ó di agbẹ́jọ́ro ní Illinois, Olórí Ẹgbẹ́ Òṣèlú Whig àti ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti lllinois ní ibi tí ó ti lo ọdún méjìlá. Wọ́n yàn án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti United States ní Ọdún 1846, Lincoln mú ìlọsíwájú ba okòwo látàrí ilé-ìfowópamọ́, owó orí ìṣòwò lókèèrè àti ojú irin.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìwé ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Burkhimer, Michael (2003). One Hundred Essential Lincoln Books. Cumberland House. ISBN 978-1-58182-369-1. 
  • Foner, Eric (2008). Our Lincoln: New Perspectives on Lincoln and His World. W.W. Norton. ISBN 978-0-393-06756-9. 
  • Holzer, Harold and Craig L. Symonds, eds. Exploring Lincoln: Great Historians Reappraise Our Greatest President (2015), essays by 16 scholars
  • Manning, Chandra, "The Shifting Terrain of Attitudes toward Abraham Lincoln and Emancipation", Journal of the Abraham Lincoln Association, 34 (Winter 2013), 18–39.
  • Smith, Adam I.P. "The 'Cult' of Abraham Lincoln and the Strange Survival of Liberal England in the Era of the World Wars", Twentieth Century British History, (Dec 2010) 21#4 pp. 486–509
  • Spielberg, Steven; Goodwin, Doris Kearns; Kushner, Tony. "Mr. Lincoln Goes to Hollywood", Smithsonian (2012) 43#7 pp. 46–53.