Jump to content

Aganju

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the spirit. Fún the song referring to the spirit, ẹ wo: Bebel Gilberto (album). Fún the historical ruler, ẹ wo: Aganju of Oyo.
Aganju
Volcanoes (Cuba / Santería), Wilderness, Desert (Cuba / Santería), River (Cuba / Santería)
Member of Orisha
Script error: The module returned a nil value. It is supposed to return an export table.
Other namesAganju
Venerated inYoruba religion, Umbanda, Candomble, Santeria, Haitian Vodou, Folk Catholicism
RegionNigeria, Benin, Brazil
Ethnic groupYoruba people, Fon people
OffspringSango
Equivalents
Catholic equivalentSaint Christopher

Àdàkọ:Yoruba people Aganju ( tí wọ́n tún ń pè ní Agayú, Aggayú, Aganjú tàbí Aganyú ni òdò awon elédèè Spanish ni wón ń pè ní Òrìṣà. Wón gbà pé ó ń ṣíṣe pọ̀ pẹ̀lú Saint Christopher nínú Ẹsin ti àwọn Cuban, èyí tí wọ́n ń pè ní Santería.

Wọ́n gbàgbọ́ pé Aganjú ni àjọṣe pẹ̀lú Òrìsà ṣàǹgó. Gẹ́gẹ́ bí Ọba ní Ọ̀yọ́ rí, Aganju jẹ́ ọmọ Ẹ̀gbọ́n Ṣàǹgó tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Àjàká. Èyí tí ó jẹ́ pé àwọn méjèèjì tí fi ìgbà kan jẹ́ Ọba ìlú Ọ̀yọ́ rí tí wọ́n ti ìpàṣẹ rẹ̀ di Òrìṣà tí wọ́n ń bọ.

Ní àwọn àgbègbè kan nílé Yorùbá ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti orílè èdè Bìnì, Aganju jẹ́ Òóṣà tí ó fi ìgbà jẹ́ Ológun àti Ọba láti ìlú Sakí, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lóde Òní nílé Nàìjíríà. Wọ́n gbà pé ó máa ń rìn pẹ̀lú Idà lọ́wọ́ àti pé ó máa ń jà pẹ̀lú Iná èyí tí ó jé pé ó fé jó tí Ṣàǹgó tí ó máa ń rán Àrá àti Mònàmóná láti fi já. Sakí jé Apá Ariwa ni ilé Yorùbá to ní àwọn òkè ńláńlá.

Santería (Lucumí/Regla de Ocha)

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní Cuba, Aganju jẹ́ Òrìṣà Oníná lódò àwọn Ẹlẹ́sìn Santeria/Lucumi. Ṣùgbọ́n kò sí Iná tí máa jó lábẹ́ ilé tí wọ́n ń pè ní Volcanoes ni Cuba tàbí nílé Yorùbá, tí Aganju fúnra rẹ̀ kò ní Ìbásepọ̀ pẹ̀lú ohun tí a sọ síwájú tí kò sì láàárín àwọn Elédè Yorùbá. Ṣùgbọ́n , ní agbègbè Biu ni Plateau, a rí àwọn òkè ńláńlá ti wón ti gbàgbé ni apá àríwá Gúúsù. Biu Ní Plateau Ṣí wá ní máílì àmọ̀yè Àdàkọ:Yípadà láti Abuja, tí ó jé Olú Ìlú ilé Nàìjíríà àti máílì bí Àdàkọ:Yí padà láti Ìpínlẹ̀ Oyo, ní orílè èdè Nàìjíríà. Àwọn òkè ńláńlá yìí tí wá ní ìgbàgbé láti ọjọ́ pípé, tí wọ́n kò sì súmọ́ ilé Yorùbá rárá. Fún ìdí èyí, a lè sọ pé Òrìṣà Aganju ni àjọṣe pẹ̀lú àwọn Òkè Ńláńlá Ilé Cuba, tí a bá sì wò ọjọ́ orí wón tàbí ìgbà tí wọ́n ti wà, a máa tó Ọgọ́rùn-ún ọdún sẹ́yìn. A tún lè sọ pé Ìbínú Òrìṣà Aganju wá ní ìbámu tàbí ní àjọṣe pẹ̀lú OroIna tí ó jẹ́ Òrìṣà kan nílé Cuba tí àwọn Yorùbá gba pe òun ni Ọ̀rànmíyán ni èdè Yorùbá

Ní orílẹ̀ èdè Brazil tí wọ́n ni ìbátan pẹ̀lu àwọn aláwọ̀ dúdú tí Ìsìn wọn fẹ́ jọ tí Candomblé, Wọ́n gbà pé Aganju a máa ṣé bí ti Òrìṣà Ṣàǹgó, èyí ló mú wọn kí wọn máa pè é ní Xango Aganjú. Aganju dúró fún ohun kan tí máa tètè bínú, tí kìí ni olùbáwí. Nítorí èyí ni wón fi ń pè ní "Xangô menino" èyí tí ó jé inagije ré lódò àwọn ará Candomblé.

Fún Ìkà síwájú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Jo Anna Hunter. Ìyánifá Ọmó̩tinúwẹ̀, “My Journey to Aganjú: The Orisa so Hard to Find “ BlackMadonnaEnterprises.com and Oro Pataki Aganju: A Cross Cultural Approach Towards the Understanding of the Fundamentos of the Orisa Aganju in Nigeria and Cuba, In Orisa Yoruba God and Spiritual Identity in Africa and the Diaspora, edited by Toyin Falola, Ann Genova. New Jersey: Africa World Press, Inc.

Àdàkọ:Alaafins of Oyo

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Brazil-myth-stub Àdàkọ:Deity-stub