Jump to content

Agbani Darego

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Agbani Darego.
Agbani Darego
Beauty pageant titleholder
Alias(es)Agbani Darego
Height1.86 m (6 ft 1 in)
Title(s)Most Beautiful Girl in Nigeria 2001
Miss World 2001

Agbani Darego (born Ibiagbanidokibubo Asenite Darego,[1] 22 December 1982), je ologe omo ile Naijiria to gba oye arewa Miss World ni odun 2001. Ohun ni ọmọ Áfríkà alawodudu akoko to je oye yi.