Ajayi Agbebaku
Ìrísí
| Òrọ̀ ẹni | |
|---|---|
| Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹfà 1955 Benin City, Nigeria |
Ajayi Agbebaku (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù Kejìlá ọdún 1955) jẹ́ eléré ìdárayá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ti fẹ̀yìntì tí ó sì dije nínú eré-ìjòkìtì-fífò-mẹ́ta . Ó ṣì ní akọsílẹ̀ àkọọ́lẹ̀ ní Yunifásítì Missouri pẹ̀lú fífò rẹ̀ ní mítà 16.60 níbi ìdíje NCAA inú ilé ní ọdún 1978.
Fífò tó dára jùlọ fún ara rẹ̀ ni mítà 17.26, ó sì ṣe é ní oṣù Keje ọdún 1983 ní Edmonton . Èyí ni àkọsílẹ̀ Nàìjíríà tí ó dára jù lọ àti ìkejì ní Áfíríkà, lẹ́yìn Ndabazinhle Mdhlongwa nìkan. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ilẹ̀ Áfíríkà nínú ilé pẹ̀lú mítà 17.00, èyí tí ó gbà ní oṣù kìíní ọdún 1982 ní Dallas.
Àwọn Àṣeyọrí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]| Representing | |||||
|---|---|---|---|---|---|
| 1979 | African Championships | Dakar, Senegal | 1st | Long jump | 7.94 m |
| 1st | Triple jump | 16.82 m | |||
| 1983 | World Championships | Helsinki, Finland | 3rd | Triple jump | 17.18 m |
| 1984 | African Championships | Rabat, Morocco | 2nd | Triple jump | 16.96 m |
| Olympic Games | Los Angeles, United States | 7th | Triple jump | 16.67 m | |