Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀
Olórí ilé-iṣé ìjọba fún àwon òṣìṣé ní ìpínlẹ̀ Èkó
In office
July 2004 – February 2006
GómìnàBọ́lá Tinúbú
Personal details
Ọjọ́ìbíOṣù Kejì 10, 1946 (1946-02-10) (ọmọ ọdún 74)
Badagry, Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèluAll Progressives Congress
Alma mater

Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá, Oṣù kejì Ọdún 1946. Ó j̣́e olóṣ̀elú àti ògá-àgbà òṣìṣẹ́ ìjọba[1] Ó ti fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-iṣé ìjọba fún àwon òṣìṣé ní ìpínlẹ̀ Èkó láti oṣù keje ọdún 2004 sí oṣù kejì ọdun 2006.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]